Author Topic: Isé ni òògùn ìsé........work is the antidote for poverty  (Read 3847 times)

MyInfoStride

 • Administrator
 • *****
 • Posts: 5555
 • Rating: +10/-0
Isé ni òògùn ìsé........work is the antidote for poverty

Múra sí isé re òréè mi....Work hard, my friend
Isé ni a fi í di eni giga.....work is used to elevate one in respect and importance (Aspiring to higher height is fully dependent on hard work)
Bí a kò bá réni fèyìn tì, Bí òle là á rí;....if we do not have anyone to lean on, we appear insolent
Bí a ko réni gbékèlé,....if we do not have anyone to trust (we can depend on...)
À tera mó isé eni.....we simply work harder
Ìyá re lè lówó lówó.....your mother may be wealthy
Bàbá sì lè lésin léèkàn.....your father may have a ranch full of horses
Bí o bá gbójú lé won,........ if you depend on their riches alone
O té tán ni mo so fún o,......you may end up in disgrace, I tell you
Ohun tí a kò ba jìyà fún,......whatever gain one does not work hard to earn.
Kì í lè tójó......usually does not last
Ohun tí a bá fara sisé fún,....whatever gain one works hard to earn
Ní í pé lówó eni.....is the one that lasts in one ' s hands.(while in one’s possession)

Apá lará, ìgùnpá nìyekan...... the arm is a relative, the elbow is a sibling
Bí ayé n fé o lónìí,....you may be loved by all today
Bí o bá lówó lówó,......it is when you have money
Ni won á máa fé o lóla......that they will love you tomorrow
Tàbí tí o bá wà ní ipò àtàtà,.....or when you are in a high position
Ayé á yé o sí tèrín-tèrín,.... .all will honor you with cheers and smiles
Jé kí o di eni n ráágó,....wait till you become poor or are struggling to get by
Kí o rí báyé ti í símú sí o......and you will see how all grimace at you as they pass you by
Èkó sì tún n soni í dògá,.....education also elevates one in position
Múra kí o kó o dáradára.....work hard to acquire good education
Bí o sì rí òpò ènìyàn,.....and if you see a lot of people
Tí wón n fi èkó se èrín rín,....making education a laughing stock
Dákun má se fara wé won.....please do not emulate or keep their company
Ìyà n be fómo tí kò gbón,.....suffering is lying in wait for an unserious kid
Ekún n be fómo tó n sá kiri.......sorrow is in the reserve for a truant kid
Má fòwúrò seré, òréè mi,.....do not play with your early years, my friend
Múra sísé, ojó n lo.....work harder, time and tide wait for no one.

The InfoStride Forum


pii

 • Baby InfoStrider
 • *
 • Posts: 11
 • Rating: +0/-0
Re: Isé ni òògùn ìsé........work is the antidote for poverty
« Reply #1 on: Oct 01, 2009, 05:38 PM »
What about if you don't have any of that antidote available?

MegaDeal

 • Chief InfoStrider
 • ****
 • Posts: 400
 • Rating: +2/-0
Re: Isé ni òògùn ìsé........work is the antidote for poverty
« Reply #2 on: Apr 04, 2010, 05:50 AM »
What about if you don't have any of that antidote available?

The antidote is always an endowment on every human being but failure to discover self makes it worst.

One salvation lies in one's hand. It is only what we gather with our sweat that stands test of time. There is no short-cut to success. It is a process that requires hardwork...

The InfoStride Forum

Re: Isé ni òògùn ìsé........work is the antidote for poverty
« Reply #2 on: Apr 04, 2010, 05:50 AM »